Kí ló dé tí mo fi nílò kẹ́mọ́tẹ́rápì bí wọ́n bá ti yọ ìṣù náà kúrò?
Iṣẹ́ abẹ ń yọ ohun tí a lè rí kúrò. Kẹ́mọ́tẹ́rápì ń dojú kọ àwọn sẹ́ẹ̀lì tí ó kéré jù láti hàn lórí àwòrán ẹ̀rọ èyíkéyìí.
A máa ń fún ọ láti dín ànfààní pé kí akàn náà padà wá kù, bí ó bá ṣẹlẹ̀ pé àwọn sẹ́ẹ̀lì díẹ̀ tí ẹnikẹ́ni kò lè rí ṣì kù.
A túmọ̀ rẹ̀ láti inú káàdì èdè Gẹ̀ẹ́sì. A ń gbèrò kí dókítà tí ó gbọ́ Yorùbá ṣàyẹ̀wò ìtúmọ̀ yìí. Orísun: National Cancer Institute